Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Ẹ̀rí fi hàn pé Éfúrátà (tàbí Éfúrátì) ni orúkọ tí wọ́n ń pe Bẹ́tílẹ́hẹ́mù tẹ́lẹ̀ rí.—Jẹ́nẹ́sísì 35:19.