Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Láti kẹ́kọ̀ọ́ púpọ̀ sí i nípa Ìjọba Ọlọ́run àti bí a ṣe mọ̀ pé yóò dé láìpẹ́, ka orí 8, ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? tó ní àkòrí náà, “Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run,” àti orí 9, tó sọ pé, “Ṣé ‘Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn’ La Wà Yìí?” Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é.