Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Jésù sábà máa ń pe ara rẹ̀ ní “Ọmọ ènìyàn.” (Mátíù 8:20) Ọ̀rọ̀ yìí fi hàn pé yàtọ̀ sí pé Jésù jẹ́ èèyàn, ó tún fi hàn pé òun ni “ọmọ ènìyàn” tí Bíbélì sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa rẹ̀.—Dáníẹ́lì 7:13, 14.