Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Láti mọ̀ púpọ̀ sí i nípa ẹ̀kọ́ Bíbélì nípa àjíǹde, ka orí 7 ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é.