Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nígbà tí ìwé gbédègbẹ́yọ̀ náà New Catholic Encyclopedia ń sọ̀rọ̀ nípa àsọtẹ́lẹ̀ yìí, ó ní: “Nígbà ìparun Jerúsálẹ́mù, ọ̀pọ̀ àwọn olùgbé ìlú yìí ló máa kú, inú àfonífojì yìí ni wọ́n máa da òkú wọn sí, wọn kò ní sin wọ́n, ibẹ̀ ni wọ́n máa jẹrà sí tàbí kí iná sun wọ́n.”