Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bó o bá fẹ́ mọ ohun tá a sọ nípa kókó yìí, wo àkìbọnú náà, “Ojú Wo Ló Yẹ Kí N Fi Wo Àwọn Oògùn Tó Ní Èròjà Ẹ̀jẹ̀ Nínú, Kí Ló sì Yẹ Kí N Ṣe Báwọn Dókítà Bá Fẹ́ Fi Ẹ̀jẹ̀ Mi Tọ́jú Mi Lọ́nà Èyíkéyìí?” nínú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa, December 2006, ojú ìwé 3 sí 6.