Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ìdààmú ọkàn máa ń bá ọ̀pọ̀ àwọn ìyá láwọn ọ̀sẹ̀ díẹ̀ lẹ́yìn tí wọ́n bímọ. Àìsàn kan tó lágbára tí wọ́n ń pè ní àbísínwín máa ń bá àwọn kan fínra. Fún ìsọfúnni síwájú sí i nípa béèyàn ṣe lè mọ̀ bí àìlera yìí bá ń ṣe ẹnì kan àti béèyàn ṣe lè fara dà á, ka àwọn àpilẹ̀kọ yìí lédè Gẹ̀ẹ́sì, ìyẹn Awake! ti July 22, 2002, tí àkòrí rẹ̀ sọ pé, “I Won My Battle With Postpartum Depression,” àti Awake! ti June 8, 2003, tí àkòrí rẹ̀ sọ pé, “Understanding Postpartum Depression.” Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é. O lè rí àwọn àpilẹ̀kọ́ yìí kà lórí ìkànnì wa www.watchtower.org.