Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Gẹ́gẹ́ bí ìwé ìwádìí kan ti wí, ọ̀rọ̀ ìṣe èdè Hébérù tí wọ́n túmọ̀ sí “fà mọ́” ní Jẹ́nẹ́sísì 2:24 ní ìtumọ̀ ‘fífi ìfẹ́ àti ìdúróṣinṣin dìrọ̀ mọ́ ẹnì kan.’