Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ó lè jẹ́ àwùjọ ìràwọ̀ Pleiades ló ń jẹ́ “àgbájọ ìràwọ̀ Kímà.” Ó lè jẹ́ pé àgbájọ ìràwọ̀ Orion ló ń jẹ́ “àgbájọ ìràwọ̀ Késílì.” Ó máa tó ẹgbẹẹgbẹ̀rún ọdún kí ìrísí àwọn ìràwọ̀ náà tó lè yí pa dà.