Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ìwé ìròyìn kan sọ pé: “Ṣọ́ọ̀ṣì Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì ti Ilẹ̀ Rọ́ṣíà ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe láti rí sí i pé ìjọba gba òfin yìí wọlé. Ṣọ́ọ̀ṣì náà kò fẹ́ kí ẹ̀sìn míì gbapò mọ́ òun lọ́wọ́, torí náà ó fẹ́ kí ìjọba fi òfin de iṣẹ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà.”—Àjọ akóròyìnjọ Associated Press, ti June 25, ọdún 1999.