Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a “Ìpẹ̀yìndà” túmọ̀ sí kíkúrò nínú ìjọsìn tòótọ́, ṣíṣubú kúrò, ìyapa-kúrò, ìṣọ̀tẹ̀, ìpatì.