Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ohun kan náà la lè sọ nípa àwọn fọ́tò tá a lè gbé sórí Íńtánẹ́ẹ̀tì. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé a lè ya fọ́tò fún ìlò tara wa, a lè máà lẹ́tọ̀ọ́ láti pín wọn kiri bó ṣe wù wá, ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ sọ pé ká sọ orúkọ àwọn tó wà nínú fọ́tò náà àti ibi tí wọ́n ń gbé fáwọn ẹlòmíì.