Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Irú ìwà yìí máa ń bí àwọn Júù ìgbàanì nínú. Gẹ́gẹ́ bí ìwé ìgbàanì kan ṣe sọ, àríyànjiyàn ńlá lèyí dá sílẹ̀ nígbà tí Jason, àlùfáà àgbà tó di apẹ̀yìndà, tó sì ń fẹ́ láti gbé àṣà àwọn Gíríìkì lárugẹ, dá a lábàá pé kí wọ́n kọ́ gbọ̀ngàn eré ìdárayá kan sí ìlú Jerúsálẹ́mù.—2 Macc. 4:7-17.