Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Kárí ayé, àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń kọ́ àwọn èèyàn tí wọ́n bá fẹ́ lóye Bíbélì lẹ́kọ̀ọ́ lọ́fẹ̀ẹ́ nínú ilé wọn. A rọ̀ ẹ́ pé kí ìwọ náà wá wọn kàn ládùúgbò rẹ tàbí kó o kọ̀wé sí àdírẹ́sì tó yẹ nínú èyí tó wà lójú ìwé 4 ìwé ìròyìn yìí.