Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe Bíbélì kan tó ṣeé gbára lé, orúkọ rẹ̀ ni Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun. Àmọ́, tó bá jẹ́ pé o kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà, o lè lo àwọn Bíbélì míì nígbà tó o bá ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a lo àwọn Bíbélì kan táwọn èèyàn máa ń lò dáadáa.