Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ilẹ̀ Ọba Bábílónì Ẹlẹ́ẹ̀kejì bẹ̀rẹ̀ nígbà tí bàbá Nebukadinésárì, ìyẹn Nabopolásárì jọba, ó sì parí nígbà ìṣàkóso Nábónídọ́sì. Àkókò yìí ṣe pàtàkì gan-an fún àwọn ọ̀mọ̀wé, nítorí pé èyí tó pọ̀ jù lára àádọ́rín ọdún tí Jerúsálẹ́mù fi wà ní ahoro ló bọ́ sí sáà àkókò náà.