Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àwòkẹ́kọ̀ọ́ òde òní kan tó dá lórí bí Kristẹni kan tó jẹ́ ọ̀dọ́ ṣe sapá láti ṣe ohun tó tọ́ lójú Jèhófà.