Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Tó o bá fẹ́ mọ̀ síwájú sí i nípa àwọn ìmọ̀ràn tó gbéṣẹ́ tó wà nínú Bíbélì, wá àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà kàn ládùúgbò rẹ. Tàbí kó o kọ̀wé sí àwọn tó ṣe ìwé yìí, wàá rí àdírẹ́sì tó o lè lò nínú èyí tó wà lójú ìwé 4 ìwé ìròyìn yìí tàbí kó o lọ sórí ìkànnì wa www.watchtower.org.