Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn òbí yóò rí ìsọfúnni tó máa ràn wọ́n lọ́wọ́ lórí àwọn kókó ẹ̀kọ́ yìí nínú ìtẹ̀jáde tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe, àwọn nìyí: Jí! October–December 2006, ojú ìwé 10 sí 13 tó ní àpilẹ̀kọ náà, “Bó O Ṣe Lè Ran Ọmọbìnrin Rẹ Lọ́wọ́ Láti Múra Sílẹ̀ De Ìgbà Tó Máa Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣe Nǹkan Oṣù”; Ìwé Awọn Ìbéèrè Tí Awọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Awọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì, orí 6 tó sọ pé, “Kí Nìdí Tára Mi Fi Ń Yí Pa Dà?” àti Ilé Ìṣọ́ November 1, 2010, ojú ìwé 12 sí 14 tó ní àpilẹ̀kọ náà, “Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Bá Ọmọ Rẹ Sọ̀rọ̀ Nípa Ìbálòpọ̀.”