Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ó dùn mọ́ni pé ọ̀gbẹ́ni Zamora lo orúkọ Ọlọ́run gangan dípò orúkọ oyè rẹ̀ nínú lẹ́tà ẹ̀bẹ̀ tó kọ sí póòpù ilẹ̀ Róòmù. “Yáwè” ni wọ́n pe orúkọ Ọlọ́run nínú lẹ́tà ẹ̀bẹ̀ ọ̀gbẹ́ni Zamora tí wọ́n tú sí èdè Sípáníìṣì. A kò lè sọ bí wọ́n ṣe kọ ọ́ ní èdè Látìn tí wọ́n fi kọ lẹ́tà náà. Fún ìsọfúnni síwájú sí i lórí iṣẹ́ ìtumọ̀ tí ọ̀gbẹ́ni Zamora ṣe àti bó ṣe lo orúkọ Ọlọ́run, wo àpótí náà, “Títúmọ̀ Orúkọ Ọlọ́run” lójú ìwé 19.