Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìwé Insight on the Scriptures ṣàlàyé pé: “Bí Ọlọ́run bá fi ìran han ẹnì kan lákòókò tí ẹni náà wà lójúfò, ńṣe ló máa ń dà bíi pé, wọ́n yàwòrán ìran náà sọ́kàn onítọ̀hún. Ẹni náà lè rántí ìṣẹ̀lẹ̀ náà tó bá yá, ó sì lè ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ tàbí kó fi ọ̀rọ̀ ara rẹ̀ ṣàkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ náà.”—Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é.