Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Wo ibi tá a ti jíròrò ọ̀kọ̀ọ̀kan ànímọ́ tó jẹ́ apá kan èso ti ẹ̀mí lábẹ́ kókó ọ̀rọ̀ náà, “Fruitage of God’s Spirit,” [Èso Ẹ̀mí Ọlọ́run] àti ibi tá a tò wọ́n sí tẹ̀ léra lábẹ́ àkòrí náà, “List by Aspect,” nínú àwọn ìwé atọ́ka tá à ń pè ní Watch Tower Publications Index.