Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àlàyé lórí bí àwọn ìwé Ìhìn Rere inú Bíbélì ṣe yàtọ̀ sí àwọn ayédèrú ìwé kan tí wọ́n kọ nípa Jésù, wà nínú àpilẹ̀kọ kan tá a pe àkòrí rẹ̀ ní “Àwọn Ìwé Ìhìn Rere Ti Àpókírífà, Ǹjẹ́ Ìtàn Jésù Tí Bíbélì Kò Sọ Ni Lóòótọ́?” ní ojú ìwé 18 àti 19.