Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Láyé ìgbà yẹn, ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé ojú ẹni tó ti ṣègbéyàwó ni wọ́n máa fi ń wo àwọn tó bá ti di àfẹ́sọ́nà.