Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Bíbélì fi hàn pé ẹ̀yìn ìgbà tí Jésù ṣe ìrìbọmi ló ṣe iṣẹ́ ìyanu àkọ́kọ́. (Jòhánù 2:1-11) Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa àwọn ìwé ìhìn rere ti àpókírífà, wo àpilẹ̀kọ náà, “Àwọn Ìwé Ìhìn Rere Ti Àpókírífà, Ǹjẹ́ Ìtàn Jésù Tí Bíbélì Kò Sọ Ni Lóòótọ́?” ní ojú ìwé 18.