Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti tẹ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé ńlá àti àwọn ìwé pẹlẹbẹ jáde tí o lè fi ṣèwádìí jinlẹ̀ nínú ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì rẹ̀. Tí o bá fẹ́ mọ̀ sí i, gbìyànjú láti wá àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ládùúgbò rẹ tàbí kí o kọ̀wé sí àwọn tó ṣe ìwé tó wà lọ́wọ́ rẹ yìí.