Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Tó bá ṣẹlẹ̀ pé fún àwọn àkókò kan, ó di dandan kó o fojú kan ẹni náà (bóyá níbi iṣẹ́), a jẹ́ pé ó gbọ́dọ̀ jẹ́ torí ohun tí kò ṣeé yẹ̀ sílẹ̀. Jẹ́ kí àwọn èèyàn wà níbẹ̀ tí nǹkan kan bá máa dà yín pọ̀, kó o sì jẹ́ kí ọkọ tàbí ìyàwó rẹ mọ gbogbo bí nǹkan bá ṣe ń lọ.