Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bíbélì pe Ebedi-mélékì ní “ìwẹ̀fà.” (Jeremáyà 38:7) Bó tilẹ̀ jẹ́ pé orúkọ yìí ni wọ́n fi ń pe ọkùnrin tí wọ́n tẹ̀ lọ́dàá, wọ́n tún ń lò ó láti fi pe onípò àṣẹ tó ń ṣiṣẹ́ ní ààfin ọba.