Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nígbà tó yá Frank Lambert, ẹ̀gbọ́n Elva di aṣáájú-ọ̀nà onítara ní orílẹ̀-èdè Ọsirélíà. Ìwé ọdọọdún àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, ìyẹn 1983 Yearbook of Jehovah’s Witnesses, ojú ìwé 110 sí 112 sọ ọ̀kan lára ọ̀pọ̀ ìrírí amóríyá tó ní nípa bó ṣe máa ń rìnrìn-àjò láti lọ ṣiṣẹ́ ìwàásù nígbà yẹn.