ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

c Dáníẹ́lì rí ìparun tó burú jáì tí ọba yìí máa fà nígbà ogun náà, ó kọ̀wé pé: “Yóò sì fa ìparun ní ọ̀nà àgbàyanu [lọ́nà tí ń bani lẹ́rù].” (Dán. 8:24) Bí àpẹẹrẹ, orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà fa ìparun tó lágbára gan-an nígbà tó ju àdó olóró méjì sí orílẹ̀-èdè kan tó jẹ́ ọ̀tá Agbára Ayé Gẹ̀ẹ́sì òun Amẹ́ríkà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́