Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tó o bá fẹ́ rí àlàyé púpọ̀ sí i nípa ẹ̀rí tó fi hàn pé Ọlọ́run wà, wo Ilé Ìṣọ́ June 1, 2004, ojú ìwé 9 sí 14; Jí! October 2006, ojú ìwé 20 sí 22; ìwé pẹlẹbẹ náà The Origin of Life—Five Questions Worth Asking àti ìwé Is There a Creator Who Cares About You? Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe wọn.