Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ó dára kí àwọn òbí bá àwọn ọmọ wọn jíròrò ohun tó wà nínú àpótí náà, “Mímúra Sílẹ̀ De Ìṣòro” tó wà ní ojú ìwé 132 sí 133 nínú ìwé Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì. Ẹ lè jíròrò rẹ̀ nígbà Ìjọsìn Ìdílé yín.