Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Lára àwọn àpilẹ̀kọ tí yóò máa jáde lórí ìkànnì nìkan ni: “Abala Àwọn Ọ̀dọ́,” tó dá lórí onírúurú ẹ̀kọ́ Bíbélì tí a dìídì ṣe fún àwọn ọ̀dọ́. Òmíràn ni “Ẹ̀kọ́ Bíbélì,” a ṣe èyí fún àwọn òbí kí wọ́n lè máa lò ó láti fi kọ́ àwọn ọmọ wọn tí kò tíì ju ọmọ ọdún mẹ́ta lọ.