Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ọ̀pọ̀ ìgbà ni Bíbélì sọ pé àwọn obìnrin wà lára àwọn tí Sọ́ọ̀lù ṣe inúnibíni sí. Èyí tó fi hàn pé àwọn obìnrin ṣe gudugudu méje nínú iṣẹ́ ìwàásù nígbà tí ẹ̀sìn Kristẹni ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀. Wọ́n ṣì ń ṣe bẹ́ẹ̀ lónìí pẹ̀lú.—Sm. 68:11.