Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Àwọn ọ̀mọ̀wé tó sọ pé ẹ̀mí èṣù ni wọ́n pe Júdásì níbi tí ìwé yìí ti sọ pé òun ló mọ Jésù dénúdénú jù láàárín àwọn àpọ́sítélì, ṣàkíyèsí pé gbólóhùn tí wọ́n lò níbẹ̀ jọ ọ̀nà tí ìwé Ìhìn Rere inú Bíbélì gbà sọ pé àwọn ẹ̀mí èṣù sọ ẹni tí Jésù jẹ́ gan-an.—Máàkù 3:11; 5:7.