Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d Ní ọdún 36 sí 37 Sànmánì Kristẹni, Tìbéríù Késárì ju Hẹ́rọ́dù Àgírípà sẹ́wọ̀n ní àgọ́ àwọn ẹ̀ṣọ́ olú ọba torí pé ó sọ pé òun fẹ́ kí Caligula di olú ọba. Nígbà tí Caligula gorí ìtẹ́, ó fi Hẹ́rọ́dù jọba Jùdíà.—Ìṣe 12:1.