Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú Bíbélì, ọ̀rọ̀ Gíríìkì tí wọ́n tú sí “àjíǹde” lédè Yorùbá túmọ̀ sí pé kí ẹni tó kú tún pa dà wà láàyè, tòun ti gbogbo ohun tó mú kó yàtọ̀ sí ẹlòmíì. Kó má sì gbàgbé àwọn ohun tó ti mọ̀ tẹ́lẹ̀ nígbà ayé rẹ̀.