Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Àwọn “àpọ́sítélì” ni ẹsẹ Bíbélì yìí pè ní “àwọn méjìlá náà,” bó tilẹ̀ jẹ́ pé mọ́kànlá ni wọ́n fúngbà díẹ̀ lẹ́yìn ikú Júdásì Ísíkáríótù. Kódà ìgbà kan wà tí Tọ́másì kò sí láàárín wọn, tó jẹ́ pé mẹ́wàá péré lára wọn ni Jésù fara hàn, síbẹ̀ wọ́n ṣì pè wọ́n ní àwọn méjìlá.—Jòhánù 20:24.