Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Orúkọ náà jẹ́ ọ̀rọ̀-ìṣe Hébérù kan tó túmọ̀ sí “di,” ìyẹn ni pé Ọlọ́run lè “di” ohunkóhun tó bá wù ú kó lè ṣe ohun tó ní lọ́kàn. Látàrí ìyẹn, orúkọ náà, “Jèhófà” túmọ̀ sí “Alèwílèṣe.”—Jẹ́n. 2:4, àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé, NW.