Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Orúkọ Jèhófà wà nínú ìwé mímọ́ lédè Hébérù táwọn Kristẹni lò ní ọ̀rúndún kìíní. Ẹ̀rí tún fi hàn pé orúkọ náà wà nínú ìtumọ̀ Septuagint, tó jẹ́ Ìwé Mímọ́ Hébérù tí wọ́n túmọ̀ sí èdè Gíríìkì.