Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn èèyàn ayé ìgbà náà lọ́hùn-ún máa ń pẹ́ láyé gan-an ju àwa ti òde òní lọ. Ìdí sì ni pé ìran wọn kò jìnnà púpọ̀ sí ti Ádámù àti Éfà tó ní ara pípé àti ìlera pípé kí wọ́n tó pàdánù rẹ̀.