a Àmọ́ ṣá o, a ò gbọ́dọ̀ gbìyànjú láti mú kí àwọn èèyàn tẹ̀ lé ohun tó wà nínú Bíbélì tipátipá, a ò sì gbọ́dọ̀ kàn wọ́n lábùkù. Àpẹẹrẹ Jèhófà ni ká máa tẹ̀ lé. Ká máa ní sùúrù fún àwọn tá à ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ká má sì fọwọ́ tó le koko mú wọn.—Sm. 103:8.