Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Tó bá wá jẹ́ pé ọ̀rọ̀ kan lo rántí nínú ẹsẹ Bíbélì yẹn, àmọ́ ti o kò rántí ìwé tó jẹ́, tó o sì ti gbàgbé orí àti ẹsẹ tó wà ńkọ́? O lè fi ọ̀rọ̀ tó o rántí yẹn wá a nínú atọ́ka tó wà lẹ́yìn Bíbélì tàbí nínú àkójọ ìtẹ̀jáde wa tó wà nínú Watchtower Library, tàbí nínú ìwé atọ́ka Bíbélì, ìyẹn Comprehensive Concordance.