Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ ìyànjú ló wà nínú lẹ́tà Pọ́ọ̀lù nípa bá a ṣe lè sá fún àwọn ohun tó lè mú wa dẹ́ṣẹ̀. (Róòmù 6:12; Gál. 5:16-18) Ó bọ́gbọ́n mu fún wa láti gbà pé òun tó ń sọ fáwọn ẹlòmíì lòun náà ń ṣe.—Róòmù 2:21.