Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ká tiẹ̀ sọ pé wọ́n tún tẹ́ńpìlì náà kọ́, èyí kò lè sọ Jésù di wòlíì èké, torí kò sọ pé wọn kò ní tún un kọ́. Ohun tó sọ ni pé wọ́n máa pa tẹ́ńpìlì náà run. Àsọtẹ́lẹ̀ yẹn sì ṣẹ lọ́dún 70 Sànmánì Kristẹni.