Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Àmọ́ o, tí ọkọ tàbí aya tí ẹ jọ kọ ara yín sílẹ̀ bá ń halẹ̀ mọ́ ẹni tí o ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ báyìí tàbí tó ń yájú sí i, ó lè gba pé kí o jẹ́ kó mọ ààlà rẹ̀, kí ilé rẹ lè tòrò.