Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀mọ̀wé gbà pé ohun tí Òfin sọ ni pé kí wọ́n kọ́kọ́ pa ọ̀daràn kan kí wọ́n tó gbé òkú rẹ̀ kọ́ sórí igi. Àmọ́ ẹ̀rí fi hàn pé nígbà tó fi máa di ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní, àwọn kan lára àwọn Júù kan àwọn ọ̀daràn kan mọ́gi láàyè, tí wọ́n á sì kú sórí igi.