Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Láyé àtijọ́, ohun èlò ìkọ̀wé ṣọ̀wọ́n, wọ́n sì gbówó lórí. Torí náà, ọ̀pọ̀ ló máa ń pa ọ̀rọ̀ tí wọ́n bá kọ sínú ìwé àfọwọ́kọ rẹ́ kí wọ́n lè tún rí ìwé náà lò láti kọ nǹkan míì. Orúkọ tí wọ́n ń pe irú àwọn ìwé àfọwọ́kọ yìí ní èdè Gíríìkì túmọ̀ sí kéèyàn nu nǹkan kúrò.