Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn àbá tó gbéṣẹ́ nípa bó o ṣe lè fún àwọn míì níṣìírí wà nínú àpilẹ̀kọ náà, “O Ha Ti Fún Ẹnikẹ́ni Ní Ìṣírí Láìpẹ́ Yìí bí?” nínú Ilé Ìṣọ́ January 15, 1995, àti “Ẹ Máa Ru Ara Yín Lọ́kàn Sókè sí Ìfẹ́ àti Sí Àwọn Iṣẹ́ Àtàtà—Báwo?” nínú Ilé Ìṣọ́ April 1, 1995.