Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ohun kan tó ṣe kedere ni pé, bí nǹkan ṣe máa rí lára ẹni tí ọkọ tàbí aya rẹ̀ kú tó wá lọ fẹ́ ẹlòmíì máa yàtọ̀ sí bó ṣe máa rí lára ẹni tó kọ ọkọ tàbí aya rẹ̀ sílẹ̀ tó wá lọ fẹ́ ẹlòmíì. Àpilẹ̀kọ yìí lè ran àwọn tó bá wà nínú irú ipò yìí lọ́wọ́ kí wọ́n lè ṣàṣeyọrí nínú ìgbéyàwó wọn tuntun.